Song info
"GRATEFUL"
(2016)
0 người yêu thích
"GRATEFUL" Videos
Lyrics
GRATEFUL (JT)
I really don't know what to say
So much I cannot repay
Melo ni n o so l'ore Re
Ti mo n ri gba l'ojojumo
O nu omije mi nu
O so mid'alayo
Ore Re ma po ninu aye mi
Standing here by your grace
From my heart I sing your praise
Mo ni Jesu ayo mi kun
O ni kin ma foya
Ki n ma beru
Nigba t'ota de, Bi riru omi
Emi Olorum gbe opagun soke
Emi yo dupe/2x Ore t'Olugbala se fun mi
Oba aye ko le se, Emi yo dupe
Tani n tun gbega o Bikose Olodumare
Tani no tun fi gbogbo Ope mi fun
Olorun to da awon oke nla ni
Iwo ni un o fi ope mi fun...
- 0 Bản dịch
Hiện tại chưa có lời dịch cho bài hát này. Bạn hãy là người đầu tiên chia sẻ lời dịch cho bài hát này nhé !
Đăng lời dịch
Recent comments